Chorus
Ask about me, ask about me (’bout me)
Wọn tí lé mí, but wọn mù mí (mu mí)
Ọmọ Ọlọrun, kólé sú mí
Seke-sekebula (‘bula)
I’m still getting my mula (mula)
Dollar pẹlú naira (naira)
Ikú tó pá ìyá teacher (teacher), ò lé pá àwọn nigga
Hook
Kí ló ńfó lókè oh? (Fó lókè)
Ẹyẹ ló ńfó lókè oh (fó lókè)
Kí ló ń rìn ni’lẹ? (Rìn ni’lẹ)
Àwọn èèyàn ló má ńrìn ni’lẹ, mà tẹ mí mọ’lẹ, oh-oh
Má tẹ ojú ilẹ mọ’lẹ, kò máà bà dọbalẹ
Ìwọ lómá f’Èkó lẹ, ko f’Èkó lẹ fún wá
Brigde
One man soldier, mẹta-mẹta, gbosa
Awilo Logomba, fún mi l’owó mí biza
Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca
I open Bible Chapter, I stepped on the Satan
Mó p’èṣù dànù, mó kàn l’ẹsẹ kàn
O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why?
Verse
They don’t know, they don’t know
They don’t know, they don’t know
I don go (they don’t know)
They wan’ know, they wan’ know
They wan’ know, they wan’ know where I’m going (I don go)
Verse
Kí ló fà frapapapa? Kí ló fà pattern yẹn?
Wọn fẹ ká mí mọ ‘bẹyẹn
Ọpọ́n tí sún finally, ọpọ́n tí sún finally
À ò bà ẹlẹ́nu méjì ṣeré mọ
Chorus
Ask about me, ask about me (’bout me)
Wọn tí lé mí, but wọn mù mí
Ọmọ Ọlọrun, kólé sú mí
Seke-sekebula (‘bula)
I’m still getting my mula (mula)
Dollar pẹlú naira (naira)
Ikú tó pá ìyá teacher (teacher), ò lé pá àwọn nigga
Hook
Kí ló ńfó lókè o? (Fó lókè)
Ẹyẹ ló ńfó lókè o (fó lókè)
Kí ló ń rìn ni’lẹ? (Rìn ni’lẹ)
Àwọn èèyàn ló má ńrìn ni’lẹ, mà tẹ mí mọ’lẹ, oh-oh
Má tẹ ojú ilẹ mọ’lẹ, kò máà bà dọbalẹ
Ìwọ lómá f’Èkó lẹ, ko f’Èkó lẹ fún wá
Bridge
One man soldier, mẹta-mẹta, gbosa
Awilo Logomba, fún mi l’owó mí biza
Kese-kese, kasa, Casa-Casablanca
I open Bible Chapter, I stepped on the Satan
Mó p’èṣù dànù, mó kàn l’ẹsẹ kàn
O tamurege, Jigan, oh-oh, why? Oh-oh, why?