Friday, December 27, 2024

Ayo Maff – 7Days [Music Video & Lyrics ]

Stream and watch 7Days by Ayo Maff [Music Video & Lyrics ]
Gbogbo owó tí mo na (oya, oya, move)Fún ọjọ’ méje (ko, kober!)Gbogbo owó tí mo naKò gbe ogungunnisọ fún mí
Èmi ọmọ oró, I no fit pass my laneWọn ni kin ma jáde, but wọn lé miÈmi ọmọ owó, I no do pass myselfWọn ni kín má sáré, but wọn le mi-iSo, I can not see my brother Ojo (Ojo o…)And popo them don lock my brother up oSay, make them free my brothers, oh-ohThem no kill person, them be ọmọ owó, oh
Ajé ogugulusọ o (ah, o kúkú ni sọ fún mi)Ah, o kúkú ni sọ fún mi (ah, o kúkú ni sọ fún mi)Ah, o kúkú ni sọ fún mi (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi)Mo mọ pe o kúkú ni sọ fún miGbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méjeMo w’ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọGbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méjeMo w’ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ
Ah, ki ikú ma pa aláàánú miKi ọta mi le ri ran woKi ọta mi le ri ran woAh, ki ikú ma pa aláàánú waKi ọta wá le ri ran woKi ọta wá le ri ran wo
Ah, ki ikú ma pa aláàánú miKi ọta mi le ri ran wo (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi)Ki ọta mi le ri ran woAh, ki ikú ma pa aláàánú waKi ọta wá le ri ran woKi ọta wá le ri ran wo
I’ve been thinking, I’ve been too deep in my feelingsBless my pocket, ṣé mi l’ọmọ t’ọ ma jí riIf I no hustle who go take care of my siblingsIf I no hustle who go take care of my siblings
Mo sare wọ Jerusalem, mo gbàdúrà ki n le pa’woIf ọlọ́pàá no lock Ojo up, my brother he dey yawoMan make man kàlàẸjẹ lo jú miMan make man kala, ahẸjẹ lo jú mi
Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méjeMo w’ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọGbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méjeMo w’ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ
Ah, ki ikú ma pa aláàánú miKi ọta mi le ri ran woKi ọta mi le ri ran woAh, ki ikú ma pa aláàánú waKi ọta wa le ri ran woKi ọta wa le ri ran wo (koba!)

Related Articles

Hot this week

Ayo Maff Biography: Age, Family, Education and Career

Ayomide Mafoluku Ayodele, better known as Ayo Maff, was...

Very dark man Biography: Age, Family, Education and Career

Martins Vincent otse, better known as very dark man,...

Does Bras Actually Prevent The Breasts From Sagging And Falling?

Many women struggle with the insecurity of sagging breasts...

Davido and Chioma to shut down US for twins’ 1 year birthday

Davido and his wife, Chioma, are reportedly planning to...

Single ladies weep as Mercy Eke’s shows off surprise gift from her mystery man

Mercy Eke, the former Big Brother Naija winner, shared...