Wednesday, February 5, 2025

Zlatan , Asake – Bust Down (Music video & Lyrics)

Stream and watch Bust Down by Zlatan , Asake (Music video & Lyrics)
Àdúrà àá gbà oh (ìbílẹ)Owó yẹn a wa oh (ayii)Bust down biza-biza lá wá, oh (jẹ kan mọ)Ọmọ ológo daya oh(Ob’, Obah)(Kaparichumarimarichopaco)(What dem-a say?)
Cash money, ọmọ iya mi, jọ (jọ)Jẹun soke, ọmọ, no dey dull (ko jọ)Cali Kush yọ eruku, we dey puff(Puff, puff, pass, my G, ma jẹ tan-n)Sometimes, me, I pray to the Lord(Let Thy will be done in my life, o dẹ jọ)Many, many things I no fit talkMoney fit me, I don’t wanna be poor
Ọmọ Iyá mi, ṣàánú miWọn ni koba ẹ, o ní ni injuryE dey gba for my body like skuriLagbaja sọ pe ko ni pẹ su miSẹntima mọkan, Sabu-SaburiNgba tẹ jẹ ojú mi, ṣé mo wa ku ni?Mi o le ja boxing, mi oun ṣe TysonWon’t you pay me? No price me (astala, astala, astala, jẹ o mọ)
Àdúrà àá gbà oh (ah, àdúrà)Owó yẹn a wa oh (ohh)Bust down, biza-biza lá wá ohỌmọ ológo daya oh (ọmọ ológo 4G)Àdúrà àá gbà oh (ah, faaji)Ehh, owó yẹn a wa oh (èèyàn Elon Musk)Bust down, biza-biza lá wá, ohỌmọ ológo daya oh
Kúrò ńbẹ, ahỌmọ ológo daya (daya)Àwọn ọlọtẹ gara, mi o kana (kana)If e no be Messiah (‘siah)Bawo ni mo ṣe ma gbe half a million dollar saya? (Saya, saya)Mi o gara, mi o kanaǸkan toju mi ri, toju ẹ ba ri, o le mayan (o le wọwi)If e no be money, apụmakaWọn fẹ gbe mi mọ ra, ẹ ma wo barawo bansa (wèrè)
Irú blessing yi kon ṣe fun ọmọ ọlẹPoverty bami po mo yọ, igo sẹ, mo yọ ọbẹṢé lo ń buga tẹlẹ, nísìnyí òun tọrọ ọkẹOnce beaten twice shy, ọlọgbọn lọlọdẹSay, if riches na drug I go take overdoseK’owo yẹn jaburata, kin ma rogún loanPalmpay agent, no near my zoneNa credit alert I wan dey see for my phone
Àdúrà àá gbà ohOwó yẹn a wa ohBust down, biza-biza lá wá ohỌmọ ológo daya ohÀdúrà àá gbà ohEhh, owó yẹn a wa ohBust down, biza-biza lá wá ohỌmọ ológo daya, oh
Mo ni, “Why tẹ n fọ pe life mi pada be like this?”Màlúù ti o niru Olúwa lo ń ba le’ṣin (lo ń ba le’ṣin)Ọmọ wèrè, Olúwa lo ń n ṣọ (lo ń ṣọ)Àá gbe igba orin, wọn ni ki la fẹ kọAh, moni pe ehn-ehn (gẹn-gẹn)Loju ọta mi, mo pada di celeb’ (ki lo wi?)Àwọn were, wọn ni mo lọ Cele (ki lo sọ?)Iku pa diet, moti yọ ẹẹkẹGbọmọ wọ nu Paris, ka lọ jaye Schengen (Espanyol)
Èmi láyé mi, ọlọba, mi o le sẹmpẹ, oh (sẹmpẹ)Ninu percen’ yẹn, mo ma jẹ ń bẹ (mo ma jẹ ń bẹ)Kẹlẹgbẹ gan má mẹgbẹ oKọrọ ẹrin ma pada dọrọ ẹlẹbẹ, ohDem say, “Industry na yeba-yebo” (yeba-yebo)Mo kọ’ti ikún si wọnMumsy ni pe kin carry goFun wọn ni gbẹdu to dun (gbẹdu to dun)Gbẹdu to dun bi edikang-ikong ati ẹba igbo
Àdúrà àá gbà ohOwó yẹn a wa ohBust down, biza-biza lá wá ohỌmọ ológo daya ohÀdúrà àá gbà, ohEhh, owó yẹn a wa ohBust down, biza-biza lá wá ohỌmọ ológo daya, oh
Focus, focusFocus, always on my grind, mo dẹ ń gbadura (ehn-ehn)Ko dùn, ko pọ, aniṣẹku la ma-ma ni lọ’lá SatiraI no fit talk, I no get stamiaMy swag is for foreigner, I want my capitalMo sare wọ Burj Khalifa, mo dẹ ń pawo nowNext stop, o di Yankee now

Related Articles

Hot this week

Ayo Maff Biography: Age, Family, Education and Career

Ayomide Mafoluku Ayodele, better known as Ayo Maff, was...

Paul Tomisin Biography: Age, Family, Education and Career

Minister Paul Tomisin is a celebrated gospel artist known...

Very dark man Biography: Age, Family, Education and Career

Martins Vincent otse, better known as very dark man,...

Does Bras Actually Prevent The Breasts From Sagging And Falling?

Many women struggle with the insecurity of sagging breasts...

Davido and Chioma to shut down US for twins’ 1 year birthday

Davido and his wife, Chioma, are reportedly planning to...